ScratchData LogoScratchData
Back to LearningKid3's profile

Scratch ni ede Yoruba

LELearningKid3•Created April 4, 2025
Scratch ni ede Yoruba
2
0
58 views
View on Scratch

Instructions

E kaabo si Scratch! Sira te si gbogbo ise ti o yan ni ise apakan ati fi sopole ni apakan sopole lati ri eniyan ni ile fun kaabo eniyan. Lati so pelu eniyan ati fi han ise re, e jo, losi apakan otito fun ile jiroro http://scratch.mit.edu/discuss/8 Lati mo bawo lo ile jiroro, ri ise yii: https://scratch.mit.edu/projects/168332076/ ===================== She fe didapo? Lati didapo, lo si “fi han ise - ile fun e kaabo gbogbo eniyan” studio (itokasi abe) ati gboran eko ni apejuwe Fi han ise re - Studio fun e kaaboo gbogbo eniyan: https://scratch.mit.edu/studios/4276585/ ===================== SHE FE SE KANKAN? Awa ko ri fun curators nissi. Ti o ba ran wa lowo, o le didapo ati di eniyan ni studio fun e kaabo gbogbo eniyan, dalohun ibeere ati fun idahun fun ise lati Scratchers ====================== E jo, mo nilo iranlowo Sho nilo iranlowo, e jo, lo si ile yii: - oju iwe fun imoran: https://scratch.mit.edu/tips - Idahun nipa Scratch: https://scratch.mit.edu/discuss/4/ - Scratch Wiki: https://en.scratch-wiki.info/ - Iranlowo pelu Scripts: https://scratch.mit.edu/discuss/7/ ====================== ilana ofin fun gbogbo eniyan: https://scratch.mit.edu/community_guidelines/ ====================== Itumo O le ri itumo ni bayi https://scratch.mit.edu/studios/25309139/ O le se itumo fun “Bawo didapo ile fun e kaabo gbogbo eniyan” Wiki irohin ni ede iwo ni!

Project Details

Project ID1157564339
CreatedApril 4, 2025
Last ModifiedApril 4, 2025
SharedApril 4, 2025
Visibilityvisible
CommentsAllowed